Showing posts with label old gospels. Show all posts
Showing posts with label old gospels. Show all posts

Monday, 18 March 2024

Ohun Baba Ṣe

Ohun Baba ṣe, ko sẹ́ni to le ṣee o

Ohun Baba ṣe, ko sẹ́ni to le ṣee o

Ẹ k'alleluya, ẹ ke hosanna si Ọlọ́run o

Ohun ti m'awọn ohun t'awa oo fẹ́

Ohun t'O ṣe fun wa, ko sẹ́ni to le ṣee o

Ohun ti m'awọn ohun t'awa oo fẹ́

Ohun t'O ṣe fun wa, ko sẹ́ni to le ṣee o


Ẹ yin in o, ẹ̀yin onigbagbo o

Ẹ yin in o, ẹ̀yin onigbagbo o

Ẹ k'alleluya, ẹ ke hosanna si Ọlọ́run o

Ohun ti m'awọn ohun t'awa oo fẹ́

Ohun t'O ṣe fun wa, ko sẹ́ni to le ṣee o

Ohun ti m'awọn ohun t'awa oo fẹ́

Ohun t'O ṣe fun wa, ko sẹ́ni to le ṣee o


Translation

What the Father has done, there's no one who can do it

What the Father has done, there's no one who can do it

Shout hallelujah, shout hosanna 

Shout hallelujah, shout hosanna to God

He has known what we would want

What He has done for us, there's no one who can do it


Praise Him, o believers

Praise Him, o believers

Shout hallelujah, shout hosanna 

Shout hallelujah, shout hosanna to God

He has known what we would want

What He has done for us, there's no one who can do it


***

Notes

I knew this song as a child in the early 90's. We sang it for a long time in church during services and thanksgiving. I believe it was popular at the time. I have no idea who the original owner of the song is, but I hope older people would know. Kindly drop the name of the writer and the minister that released this song back then if you know. Thank you.

Thursday, 2 June 2016

Gbe Ga, Gbe Ga o (Exalt, Exalt)

Gbe ga, gbe ga
Ba mi gb'Oluwa ga
Gbe ga, gbe ga
Ba mi gbe Jesu ga
Oba to mu'gbala waye se Jesu l'Oba
Ise owo Re o l'onka, iyebiye ni.

Saturday, 3 October 2015

Ta Lo Dabi Re, Jesu? 

Ta lo dabi Re, Jesu?
Ta lo dabi Re o, alagbara?
[Repeat]
Oba to gbe ogo kari ogo o:
Lati'nu ogo lo sinu ogo.
Oba ti kii sun, Oba ti kii re,
Ta lo dabi Re o, alagbara?

Translation

Who is like You, Jesus?
Who is like You, Powerful One?
[Repeat]
The King who places glory upon glory,
Escalading from glory to glory.
The King that does not sleep,
The King that tires not.
Who is like You oh, Powerful One?

Ta Lo Dabi Olorun Wa

Ta lo dabi,  ta lo dabi Olorun wa?/2×
Ta lo dabi Olorun wa, t'O seleri
T'O muleri se?

Olubukun, olubukun ni Baba,
Olubukun, olubukun ni Olorun,
Olubukun ni Emi Mimo,
Olubukun ni Metalokan.

Translation

Who is like, who is like unto our God?/2×
Who is like unto our God, who promises
And does what He says?

Blessed be, blessed be the Father,
Blessed be, blessed be the Son,
Blessed be the Holy Spirit,
Blessed be the Holy Trinity.